Omi, The water cycle, Yoruba

Science Center Objects

Ètò Ìsònyíká-omi-aláìdékun, The natural water cycle, Yoruba

Tí ìwo ba lérò wípé Omi títun pinni-pinni ni gbo-gbo Omi-ojò tí n rò wálè láti Ojúu-sánmà tàbí Omi inu Ife tí ìwo n mun déé-déé, kò rí béè rárá. Nítorípé àti Àsèdáyé ni Omi ti n be níhìín. Èyíìyí ni à n pè ní. Ètò Ìsònyíká-omi-aláìdékun.

Ètò Ìsònyíká-omi-aláìdékun - The Water Cycle, Yoruba

Ètò Ìsònyíká-omi-aláìdékun - The Water Cycle, Yoruba

Credit: USGS, Public domain

► Ètò ìs̩ò̩nyíká-omi-aláìdé̩kun fún àwon̩ o̩mo̩dé - The Water Cycle for Schools, Yoruba