Ètò ìs̩ò̩nyíká-omi-aláìdé̩kun fún àwon̩ o̩mo̩dé - Water Cycle, Yoruba

Detailed Description
Ètò ìs̩ò̩nyíká-omi-aláìdé̩kun fún àwon̩ o̩mo̩dé
The Water Cycle for Kids, Yorùbá.
Àwo̩n Ilé-is̩é̩e̩ U.S. tí ń s̩e ìwádíi nípa Ayédídá (USGS) pè̩lú ìgbìmò̩ ò̩gbìn ti Orílè̩-ède àgbáyé (FAO) ti jùmò̩ s̩e àwòjúwee ètò ìs̩ò̩nyíká-omi-aláìdé̩kun yìí fún àwo̩n Ilé-ìwé
Sources/Usage
Public Domain.