Skip to main content
U.S. flag

An official website of the United States government

Ètò ìs̩ò̩nyíká-omi-aláìdé̩kun fún àwon̩ o̩mo̩dé-Water Cycle,Yoruba PDF

Detailed Description

Ètò ìs̩ò̩nyíká-omi-aláìdé̩kun fún àwon̩ o̩mo̩dé-
The Water Cycle for Kids, Yorùbá.

Tí ìwo ba lérò wípé Omi títun pinni-pinni ni gbo-gbo Omi-ojò tí n rò wálè láti Ojúu-sánmà tàbí Omi inu Ife tí ìwo n mun déé-déé, 
kò rí béè rárá. Nítorípé àti Àsèdáyé ni Omi ti n be níhìín. Èyíìyí ni à n pè ní. Ètò Ìsònyíká-omi-aláìdékun

Sources/Usage

Public Domain.