Ètò Ìsònyíká-omi-aláìdékun - The Water Cycle, Yoruba
Ètò Ìsònyíká-omi-aláìdékun, The water cycle for schools, Yoruba
Tí ìwo ba lérò wípé Omi títun pinni-pinni ni gbo-gbo Omi-ojò tí n rò wálè láti Ojúu-sánmà tàbí Omi inu Ife tí ìwo n mun déé-déé, kò rí béè rárá. Nítorípé àti Àsèdáyé ni Omi ti n be níhìín. Èyíìyí ni à n pè ní. Ètò Ìsònyíká-omi-aláìdékun.
Ètò ìs̩ò̩nyíká-omi-aláìdé̩kun fún àwon̩ o̩mo̩dé
- Ìsù-iná Oòrún ní ń pèsè Agbára ti Ètò Ìsònyíká-omi-aláìdékun náà fi ń sisé..
- Oòrùn máa ń so Omi-òkun da Òyì-omi.
- Òyì-omi yìí, tí a kò leè fí Ojú-lásán rí yíò félo sí òkè, láti dé ibi ti Afé tútù tí à ń pè ní Òyì-ojúayé wà.
- Òyì-omi yìí yíò wá sè láti da Sánmà.
- Awon Ìfẹ̀-ilẹ̀ máa ń yo Èérú-omi jáde, tí ó sì máa ń da Sánmà.
- Àwon Ìjì-afé ló ń gbé sańmà káàkiri jákè-jádò Aye.
- Àwon Èkón-omi ní ń di Sánmà, kí wón to silè láti padà wá rò (bí Òjò àti Yìnyín).
- Ní àwon Orílè-èdè olójúojó-tútù, àwon Ìsilè wònyí ní ń padà da Yìnyín, Ìdì-omi, ati Yìnyín-òkègíga.
- Tí Yìnyín bá yó, ó lè da Ìsòn-omi, tí yíò máa sòn sínú Odò, sínú Òkun àti sínú Ilè.
- Ìdì-omi tàbí Yìnyín diè yíò fénù tààrà sínú Afé láì yó rárá (Ìfòrònù).
- Omi-òjò máa ń sòn láti Òkè-òkìtì wá sísàlè, èyíyìí ló ń túnbò máa ń sòn kún àwon Adágún-odò, àwon Odò, àti àwon Òkun..
- Òjò díè ń rin sínú Ilè, gégébíi Èsélásònlo, sùgbón èyíìyí leè mú Omi-inúilè pòsi tí ó bá jìntó.
- Omi inúu Adágún-odò ati ti inúu Odò leè rin sínú Ilè.
- Omi ń sòn lábé-ilè nítoríi Agbára Òòfà-ilè àti Agbára-ìtí.
- Àwon Ògbìn máa ń fa Omi-inúilè tí ó bá súnmó Òke-ilè sínú ara won.
- Díè nínúu Omi-inúilè ń sòn sínúu Odò àti inúi Adágún-odò, nítorínáàn ń wón lù máa sòn wá sí òkè bíi Orísun-odò.
- Àwon Ògbìn ń fa Omi-inúilè sínú ara won láti pàdánùu rè nípa lílo Ewée won láti fé Òyì-omi nù.
- Díẹ̀ nínú Omi-inúilè ń sòn-jìnlè si níbi tí ń won yíò gbé wà fún ìgbà-pípé.
- Omi-inúilè yíò sì tún padà sòn sí inú àwon Òkun, kí Ètò Ìsònyíká-omi-aláìdékun bàa lè máa bá Isé Ase-ìsetán náà lo..
Yoruba translation by Babátólá Alóba
Omi, The water cycle, Yoruba
Ètò Ìsònyíká-omi-aláìdékun - The Water Cycle, Yoruba
Ètò ìs̩ò̩nyíká-omi-aláìdé̩kun fún àwon̩ o̩mo̩dé
The Water Cycle for Kids, Yorùbá.
Àwo̩n Ilé-is̩é̩e̩ U.S. tí ń s̩e ìwádíi nípa Ayédídá (USGS) pè̩lú ìgbìmò̩ ò̩gbìn ti Orílè̩-ède àgbáyé (FAO) ti jùmò̩ s̩e àwòjúwee ètò ìs̩ò̩nyíká-omi-aláìdé̩kun yìí fún àwo̩n Ilé-ìwé